Ìtàn
Ìrísí
Kini je Itàn?
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ìtàn ni ìgbékalẹ̀ tàbí sísọ nípa àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ohun tí ó ti kọjá. Yòóbá bọ̀, wọ́n ní "bọ́mọdé kò bá gbọ́tàn, a gbọ́ àrọ́bá...." Ìtàn lè wà ní àkọsílẹ̀ tàbí kí ó máà ní àkọsílẹ̀. Ìtàn máa ń jẹ́ kí a mọ àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ méèlegbàgbé tí ó ṣẹlẹ̀ nígbà tí ènìyàn kò sí láyé tàbí wà níbi ìṣẹ̀lẹ̀ náà. [1] [2]
Itan ti ran wa lowo lati mo awon ohun ti awa ti ri làélaé. Laisi itan, awa ko le mo awon itan wa, nibo awa wa lati, tabi awon baba nla wa. Awon itàn sofun wa, bawo agbayé ti da, bawo awon ohun ti wa mu ni lapapo. Itan se pataki ju, fun wa ati fun gbogbo èniyàn. Laisi itàn agbayé ma je yato.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Hirst, K. Kris (2009-05-19). "What Is History, Anyway? A Handful of Historians Explain". ThoughtCo. Retrieved 2020-01-06.
- ↑ "What is History & Why Study It?". siena.edu. 2014-02-01. Archived from the original on 2014-02-01. Retrieved 2020-01-06. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |